YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 Lẹ́tà Kìíní sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ìkíni (1-3) Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nítorí àwọn ará Kọ́ríńtì (4-9) Ó gbà wọ́n níyànjú pé kí wọ́n wà níṣọ̀kan (10-17) Kristi, agbára àti ọgbọ́n Ọlọ́run (18-25) Ẹ máa yangàn nínú Jèhófà nìkan (26-31) 2 Iṣẹ́ ìwàásù Pọ́ọ̀lù ní Kọ́ríńtì (1-5) Ọgbọ́n Ọlọ́run ju ti èèyàn lọ (6-10) Ẹni tara àti ẹni tẹ̀mí (11-16) 3 Àwọn ará Kọ́ríńtì ṣì jẹ́ ẹni tara (1-4) Ọlọ́run ń mú kó dàgbà (5-9) Alábàáṣiṣẹ́ pẹ̀lú Ọlọ́run (9) Fi ohun tí kò lè jóná kọ́lé (10-15) Ẹ̀yin ni tẹ́ńpìlì Ọlọ́run (16, 17) Ọgbọ́n ayé jẹ́ òmùgọ̀ lọ́dọ̀ Ọlọ́run (18-23) 4 Ó yẹ kí ìríjú jẹ́ olóòótọ́ (1-5) Ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀ àwọn òjíṣẹ́ tó jẹ́ Kristẹni (6-13) ‘Má ṣe kọjá ohun tó wà lákọsílẹ̀’ (6) Àwọn Kristẹni jẹ́ ìran àpéwò (9) Pọ́ọ̀lù ń bójú tó àwọn tó jẹ́ ọmọ rẹ̀ nípa tẹ̀mí (14-21) 5 Ẹjọ́ ìṣekúṣe tó wáyé (1-5) Ìwúkàrà díẹ̀ ló ń mú gbogbo ìṣùpọ̀ wú (6-8) Ẹ mú ẹni burúkú náà kúrò (9-13) 6 Àwọn ará ń gbéra wọn lọ sílé ẹjọ́ (1-8) Àwọn tí kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run (9-11) Ẹ máa yin Ọlọ́run lógo nínú ara yín (12-20) “Ẹ máa sá fún ìṣekúṣe!” (18) 7 Ìmọ̀ràn fún àwọn tí kò gbéyàwó àti àwọn tó ti gbéyàwó (1-16) Ẹ wà ní ipò tí ẹ wà nígbà tí a pè yín (17-24) Àwọn tí kò gbéyàwó àti àwọn opó (25-40) Àǹfààní tó wà nínú kéèyàn wà láìgbéyàwó (32-35) Gbéyàwó “kìkì nínú Olúwa” (39) 8 Ọ̀rọ̀ nípa oúnjẹ tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà (1-13) Ní tiwa, Ọlọ́run kan ṣoṣo ló wà (5, 6) 9 Àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù nínú iṣẹ́ àpọ́sítélì (1-27) “O ò gbọ́dọ̀ di ẹnu akọ màlúù” (9) ‘Mo gbé tí mi ò bá wàásù!’ (16) Mo di ohun gbogbo fún gbogbo èèyàn (19-23) Bí a ṣe lè kíyè sára nínú eré ìje ìyè (24-27) 10 Àpẹẹrẹ ìkìlọ̀ látinú ìtàn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (1-13) Àpẹẹrẹ ìkìlọ̀ nípa ìbọ̀rìṣà (14-22) Tábìlì Jèhófà àti tábìlì àwọn ẹ̀mí èṣù (21) Òmìnira àti gbígba tàwọn ẹlòmíì rò (23-33) “Ẹ máa ṣe ohun gbogbo fún ògo Ọlọ́run” (31) 11 “Ẹ máa fara wé mi” (1) Ipò orí àti bíbo orí (2-16) Ṣíṣe Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa (17-34) 12 Ẹ̀bùn ti ẹ̀mí (1-11) Ara kan, ẹ̀yà ara púpọ̀ (12-31) 13 Ìfẹ́ jẹ́ ọ̀nà tó ta yọ (1-13) 14 Àwọn ẹ̀bùn ìsọtẹ́lẹ̀ àti èdè àjèjì (1-25) Àwọn ìjọ Kristẹni tó wà létòlétò (26-40) Àyè àwọn obìnrin nínú ìjọ (34, 35) 15 Àjíǹde Kristi (1-11) Àjíǹde jẹ́ ìpìlẹ̀ ìgbàgbọ́ (12-19) Àjíǹde Kristi jẹ́ àmì ìdánilójú (20-34) Ara ìyára àti ara tẹ̀mí (35-49) Àìkú àti àìdíbàjẹ́ (50-57) Ẹ ní ohun púpọ̀ láti ṣe nínú iṣẹ́ Olúwa (58) 16 Wọ́n kó nǹkan jọ fún àwọn Kristẹni tó wà ní Jerúsálẹ́mù (1-4) Ètò ìrìn àjò Pọ́ọ̀lù (5-9) Ó ṣètò bí Tímótì àti Àpólò ṣe máa bẹ àwọn ará wò (10-12) Ọ̀rọ̀ ìyànjú àti ìkíni (13-24) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ 1 Kọ́ríńtì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) 1 Kọ́ríńtì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá 1 Kọ́ríńtì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt 1 Kọ́ríńtì ojú ìwé 1519-1520