YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 Lẹ́tà Kìíní sí Tímótì Orí 1 2 3 4 5 6 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ìkíni (1, 2) Ìkìlọ̀ torí àwọn olùkọ́ èké (3-11) Inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí a fi hàn sí Pọ́ọ̀lù (12-16) Ọba ayérayé (17) ‘Máa ja ogun rere’ (18-20) 2 Gbàdúrà nítorí onírúurú èèyàn (1-7) Ọlọ́run kan, alárinà kan (5) Ìràpadà tó bá a mu rẹ́gí fún gbogbo èèyàn (6) Àwọn ìtọ́ni fún tọkùnrin tobìnrin (8-15) Múra lọ́nà tó bójú mu (9, 10) 3 Ohun tí alábòójútó gbọ́dọ̀ dójú ìlà rẹ̀ (1-7) Ohun tí ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́ gbọ́dọ̀ dójú ìlà rẹ̀ (8-13) Àṣírí mímọ́ ti ìfọkànsin Ọlọ́run (14-16) 4 Ẹ máa ṣọ́ra torí ẹ̀kọ́ àwọn ẹ̀mí èṣù (1-5) Bí o ṣe lè jẹ́ òjíṣẹ́ rere fún Kristi (6-10) Ìyàtọ̀ tó wà láàárín eré ìmárale àti ìfọkànsin Ọlọ́run (8) Máa kíyè sí ẹ̀kọ́ rẹ (11-16) 5 Bí o ṣe máa hùwà sí àwọn ọ̀dọ́ àtàwọn àgbà (1, 2) Máa ran àwọn opó lọ́wọ́ (3-16) Pèsè fún ìdílé rẹ (8) Bọlá fún àwọn alàgbà tó ń ṣiṣẹ́ kára (17-25) ‘Máa mu wáìnì díẹ̀ torí inú rẹ’ (23) 6 Kí àwọn ẹrú máa bọlá fún ọ̀gá wọn (1, 2) Àwọn olùkọ́ èké àti ìfẹ́ owó (3-10) Àwọn ìtọ́ni fún èèyàn Ọlọ́run (11-16) Máa ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ rere (17-19) Máa ṣọ́ ohun tí a fi sí ìkáwọ́ rẹ (20, 21) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ 1 Tímótì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) 1 Tímótì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá 1 Tímótì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt 1 Tímótì ojú ìwé 1581