YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 17 18 19 20 21 22 23 24 25 Ìwé Àwọn Ọba Kejì Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 17 18 19 20 21 22 23 24 25 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Èlíjà sọ tẹ́lẹ̀ pé Ahasáyà máa kú (1-18) 2 Ọlọ́run fi ìjì gbé Èlíjà lọ sókè (1-18) Èlíṣà rí ẹ̀wù Èlíjà gbà (13, 14) Èlíṣà wo omi Jẹ́ríkò sàn (19-22) Àwọn bíárì pa àwọn ọmọdékùnrin tó jáde wá láti Bẹ́tẹ́lì (23-25) 3 Jèhórámù di ọba Ísírẹ́lì (1-3) Móábù ṣọ̀tẹ̀ sí Ísírẹ́lì (4-25) Wọ́n ṣẹ́gun Móábù (26, 27) 4 Èlíṣà sọ òróró opó kan di púpọ̀ (1-7) Obìnrin ará Ṣúnémù ṣe àlejò (8-16) Obìnrin kan rí ọmọ bí; ọmọ náà kú (17-31) Èlíṣà jí ọmọ tó kú dìde (32-37) Èlíṣà mú kí ọbẹ̀ kan ṣeé jẹ (38-41) Èlíṣà sọ búrẹ́dì di púpọ̀ (42-44) 5 Èlíṣà wo ẹ̀tẹ̀ Náámánì sàn (1-19) Ẹ̀tẹ̀ kọ lu Géhásì olójúkòkòrò (20-27) 6 Èlíṣà mú kí irin àáké léfòó (1-7) Èlíṣà àti àwọn ará Síríà (8-23) Ojú ìránṣẹ́ Èlíṣà là (16, 17) Ojú inú àwọn ará Síríà fọ́ (18, 19) Ìyàn mú ní Samáríà nígbà tí wọ́n dó tì í (24-33) 7 Èlíṣà sọ tẹ́lẹ̀ pé ìyàn máa dópin (1, 2) Wọ́n rí oúnjẹ ní ibùdó tí àwọn ará Síríà ti sá kúrò (3-15) Àsọtẹ́lẹ̀ Èlíṣà ṣẹ (16-20) 8 Wọ́n dá ilẹ̀ obìnrin ará Ṣúnémù pa dà fún un (1-6) Èlíṣà, Bẹni-hádádì àti Hásáẹ́lì (7-15) Jèhórámù di ọba Júdà (16-24) Ahasáyà di ọba Júdà (25-29) 9 Wọ́n fòróró yan Jéhù ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì (1-13) Jéhù pa Jèhórámù àti Ahasáyà (14-29) Wọ́n pa Jésíbẹ́lì; àwọn ajá jẹ ẹran ara rẹ̀ (30-37) 10 Jéhù pa agbo ilé Áhábù (1-17) Jèhónádábù dara pọ̀ mọ́ Jéhù (15-17) Jéhù pa àwọn olùjọ́sìn Báálì (18-27) Àkópọ̀ ìṣàkóso Jéhù (28-36) 11 Ataláyà fi ipá gba ìtẹ́ (1-3) Wọ́n fi Jèhóáṣì jọba ní bòókẹ́lẹ́ (4-12) Wọ́n pa Ataláyà (13-16) Àwọn àtúnṣe tí Jèhóádà ṣe (17-21) 12 Jèhóáṣì di ọba Júdà (1-3) Jèhóáṣì tún tẹ́ńpìlì ṣe (4-16) Àwọn ará Síríà gbógun wá (17, 18) Wọ́n pa Jèhóáṣì (19-21) 13 Jèhóáhásì di ọba Ísírẹ́lì (1-9) Jèhóáṣì di ọba Ísírẹ́lì (10-13) Èlíṣà dán ìtara Jèhóáṣì wò (14-19) Ikú Èlíṣà; egungun rẹ̀ jí ọkùnrin kan dìde (20, 21) Àsọtẹ́lẹ̀ tí Èlíṣà sọ kẹ́yìn ṣẹ (22-25) 14 Amasááyà di ọba Júdà (1-6) Ó bá Édómù àti Ísírẹ́lì jà (7-14) Ikú Jèhóáṣì ọba Ísírẹ́lì (15, 16) Ikú Amasááyà (17-22) Jèróbóámù Kejì di ọba Ísírẹ́lì (23-29) 15 Asaráyà di ọba Júdà (1-7) Àwọn ọba tó jẹ kẹ́yìn ní Ísírẹ́lì: Sekaráyà (8-12), Ṣálúmù (13-16), Ménáhémù (17-22), Pekaháyà (23-26), Pékà (27-31) Jótámù di ọba Júdà (32-38) 16 Áhásì di ọba Júdà (1-6) Áhásì fún àwọn ará Ásíríà ní àbẹ̀tẹ́lẹ̀ (7-9) Áhásì ṣe irú pẹpẹ àwọn abọ̀rìṣà (10-18) Ikú Áhásì (19, 20) 17 Hóṣéà di ọba Ísírẹ́lì (1-4) Wọ́n ṣẹ́gun Ísírẹ́lì (5, 6) Ísírẹ́lì lọ sí ìgbèkùn nítorí pé ó di apẹ̀yìndà (7-23) Wọ́n kó àwọn àjèjì wá sí àwọn ìlú Samáríà (24-26) Àwọn ará Samáríà ń ṣe oríṣiríṣi ẹ̀sìn (27-41) 18 Hẹsikáyà di ọba Júdà (1-8) Bí wọ́n ṣe ṣẹ́gun Ísírẹ́lì (9-12) Senakérúbù wá gbéjà ko Júdà (13-18) Rábúṣákè pẹ̀gàn Jèhófà (19-37) 19 Hẹsikáyà wá ìrànlọ́wọ́ Ọlọ́run lọ́dọ̀ Àìsáyà (1-7) Senakérúbù halẹ̀ mọ́ Jerúsálẹ́mù (8-13) Àdúrà Hẹsikáyà (14-19) Àìsáyà sọ ìdáhùn Ọlọ́run fún un (20-34) Áńgẹ́lì pa 185,000 àwọn ará Ásíríà (35-37) 20 Àìsàn Hẹsikáyà àti bí ara rẹ̀ ṣe yá (1-11) Àwọn òjíṣẹ́ láti Bábílónì (12-19) Ikú Hẹsikáyà (20, 21) 21 Mánásè di ọba Júdà; ó ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ (1-18) Wọ́n máa pa Jerúsálẹ́mù run (12-15) Ámọ́nì di ọba Júdà (19-26) 22 Jòsáyà di ọba Júdà (1, 2) Bí wọ́n ṣe máa tún tẹ́ńpìlì ṣe (3-7) Wọ́n rí ìwé Òfin (8-13) Húlídà sọ tẹ́lẹ̀ pé àjálù máa ṣẹlẹ̀ (14-20) 23 Àwọn àtúnṣe tí Jòsáyà ṣe (1-20) Wọ́n ṣe Ìrékọjá (21-23) Àwọn àtúnṣe míì tí Jòsáyà ṣe (24-27) Ikú Jòsáyà (28-30) Jèhóáhásì di ọba Júdà (31-33) Jèhóákímù di ọba Júdà (34-37) 24 Jèhóákímù ṣọ̀tẹ̀, ó sì kú (1-7) Jèhóákínì di ọba Júdà (8, 9) Ìgbà àkọ́kọ́ tí wọ́n kó wọn lọ sí Bábílónì (10-17) Sedekáyà di ọba Júdà; ó ṣọ̀tẹ̀ (18-20) 25 Nebukadinésárì dó ti Jerúsálẹ́mù (1-7) Ìparun Jerúsálẹ́mù àti tẹ́ńpìlì rẹ̀; wọ́n kó wọn lọ nígbà kejì (8-21) Wọ́n fi Gẹdaláyà ṣe gómìnà (22-24) Wọ́n pa Gẹdaláyà; àwọn èèyàn sá lọ sí Íjíbítì (25, 26) Wọ́n tú Jèhóákínì sílẹ̀ ní Bábílónì (27-30) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ 2 Àwọn Ọba—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) 2 Àwọn Ọba—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá 2 Àwọn Ọba—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt 2 Àwọn Ọba ojú ìwé 512-513