YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 Lẹ́tà Kejì sí Tímótì Orí 1 2 3 4 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ìkíni (1, 2) Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run torí ìgbàgbọ́ Tímótì (3-5) Jẹ́ kí ẹ̀bùn Ọlọ́run máa jó bí iná (6-11) Máa tẹ̀ lé àwọn ọ̀rọ̀ tó ṣàǹfààní (12-14) Àwọn ọ̀tá Pọ́ọ̀lù àtàwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ (15-18) 2 Fi ọ̀rọ̀ náà síkàáwọ́ àwọn ọkùnrin tó kúnjú ìwọ̀n (1-7) Jìyà nítorí ìhìn rere (8-13) Máa lo ọ̀rọ̀ Ọlọ́run bó ṣe yẹ (14-19) Sá fún àwọn ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ìgbà ọ̀dọ́ (20-22) Ohun tí o lè ṣe sí àwọn alátakò (23-26) 3 Nǹkan máa le gan-an ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn (1-7) Tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù pẹ́kípẹ́kí (8-13) “Má ṣe fi àwọn nǹkan tí o ti kọ́ sílẹ̀” (14-17) Gbogbo Ìwé Mímọ́ ni Ọlọ́run mí sí (16) 4 “Ṣe iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ láìkù síbì kan” (1-5) Wàásù ọ̀rọ̀ náà láìfi falẹ̀ (2) “Mo ti ja ìjà rere náà” (6-8) Àwọn ọ̀rọ̀ ara ẹni (9-18) Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (19-22) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ 2 Tímótì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) 2 Tímótì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá 2 Tímótì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt 2 Tímótì ojú ìwé 1587