Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Lẹ́tà sí Àwọn Ará Gálátíà

Orí

1 2 3 4 5 6

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Ìkíni (1-5)

    • Kò sí ìhìn rere míì (6-9)

    • Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni ìhìn rere tí Pọ́ọ̀lù ń wàásù ti wá (10-12)

    • Bí Pọ́ọ̀lù ṣe yí pa dà àti àwọn ohun tó kọ́kọ́ ṣe (13-24)

  • 2

    • Pọ́ọ̀lù lọ bá àwọn àpọ́sítélì ní Jerúsálẹ́mù (1-10)

    • Pọ́ọ̀lù bá Pétérù (Kéfà) wí (11-14)

    • A pè wá ní olódodo nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ (15-21)

  • 3

    • Àwọn iṣẹ́ Òfin àti ìgbàgbọ́ (1-14)

      • Ìgbàgbọ́ yóò mú kí olódodo wà láàyè (11)

    • Ìlérí Ọlọ́run fún Ábúráhámù kì í ṣe nípasẹ̀ Òfin (15-18)

      • Kristi, ọmọ Ábúráhámù (16)

    • Ibi tí Òfin ti wá àti ohun tó wà fún (19-25)

    • Àwọn ọmọ Ọlọ́run nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ (26-29)

      • Àwọn tó jẹ́ ti Kristi jẹ́ ọmọ Ábúráhámù (29)

  • 4

    • Ẹ kì í ṣe ẹrú mọ́, ọmọ ni yín (1-7)

    • Ọ̀rọ̀ àwọn ará Gálátíà jẹ Pọ́ọ̀lù lógún (8-20)

    • Hágárì àti Sérà: májẹ̀mú méjì (21-31)

      • Jerúsálẹ́mù ti òkè ní òmìnira, òun sì ni ìyá wa (26)

  • 5

    • Òmìnira Kristẹni (1-15)

    • Ẹ máa rìn nípa ẹ̀mí (16-26)

  • 6

    • Ẹ máa bá ara yín gbé ẹrù (1-10)

      • Ohun tí èèyàn bá gbìn ló máa ká (7, 8)

    • Ìdádọ̀dọ́ kò ṣàǹfààní (11-16)

      • Ẹ̀dá tuntun (15)

    • Ìparí (17, 18)