YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 Lẹ́tà sí Àwọn Hébérù Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ọlọ́run ń sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ Ọmọ rẹ̀ (1-4) Ọmọ ju àwọn áńgẹ́lì lọ (5-14) 2 Ká túbọ̀ máa fiyè sí àwọn ohun tí a gbọ́ (1-4) A fi ohun gbogbo sábẹ́ Jésù (5-9) Jésù àti àwọn arákùnrin rẹ̀ (10-18) Olórí Aṣojú ìgbàlà wọn (10) Àlùfáà àgbà tó jẹ́ aláàánú (17) 3 Jésù ju Mósè lọ (1-6) Ọlọ́run ló kọ́ ohun gbogbo (4) Ìkìlọ̀ nípa àìnígbàgbọ́ (7-19) “Lónìí, tí ẹ bá fetí sí ohùn rẹ̀” (7, 15) 4 Ohun tí kò jẹ́ kí wọ́n wọnú ìsinmi Ọlọ́run (1-10) Ká sapá ká lè wọnú ìsinmi Ọlọ́run (11-13) Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run wà láàyè (12) Jésù, àlùfáà àgbà tó tóbi (14-16) 5 Jésù tóbi ju àwọn èèyàn tó jẹ́ àlùfáà àgbà lọ (1-10) Ní ọ̀nà ti Melikisédékì (6, 10) Ó kọ́ ìgbọràn látinú ìyà tó jẹ (8) A máa ní ìgbàlà àìnípẹ̀kun nípasẹ̀ rẹ̀ (9) Ìkìlọ̀ nípa àìdàgbà nípa tẹ̀mí (11-14) 6 Ká tẹ̀ síwájú, ká sì dàgbà nípa tẹ̀mí (1-3) Àwọn tó yẹsẹ̀ tún kan Ọmọ mọ́gi (4-8) Ẹ jẹ́ kí ìrètí yín dá yín lójú (9-12) Ìlérí Ọlọ́run dájú (13-20) Ìlérí Ọlọ́run àti ohun tó búra ò lè yí pa dà (17, 18) 7 Melikisédékì, ọba àti àlùfáà tó ṣàrà ọ̀tọ̀ (1-10) Bí Jésù ṣe jẹ́ àlùfáà tó tóbi jù (11-28) Kristi lè gbani là pátápátá (25) 8 Àgọ́ ìjọsìn tó jẹ mọ́ nǹkan ti ọ̀run (1-6) Ìyàtọ̀ tó wà láàárín májẹ̀mú ti tẹ́lẹ̀ àti májẹ̀mú tuntun (7-13) 9 Ìjọsìn mímọ́ ní ibi mímọ́ tó wà láyé (1-10) Kristi wọ ọ̀run pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ (11-28) Alárinà májẹ̀mú tuntun (15) 10 Fífi ẹran rúbọ ò gbéṣẹ́ (1-4) Òfin jẹ́ òjìji (1) Kristi rúbọ lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún ní ṣe é mọ́ láé (5-18) Ọ̀nà àbáwọlé tuntun tó jẹ́ ọ̀nà ìyè (19-25) Ká má ṣe máa kọ ìpàdé wa sílẹ̀ (24, 25) Ìkìlọ̀ nípa ẹ̀ṣẹ̀ tí a mọ̀ọ́mọ̀ dá (26-31) Ìgboyà àti ìgbàgbọ́ máa jẹ́ ká lè fara dà á (32-39) 11 Ohun tí ìgbàgbọ́ túmọ̀ sí (1, 2) Àwọn àpẹẹrẹ ìgbàgbọ́ (3-40) Kò ṣeé ṣe láti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run dáadáa láìsí ìgbàgbọ́ (6) 12 Jésù ni Aláṣepé ìgbàgbọ́ wa (1-3) Àwọsánmà àwọn ẹlẹ́rìí (1) Má fojú kéré ìbáwí látọ̀dọ̀ Jèhófà (4-11) Ẹ ṣe ọ̀nà tó tọ́ fún ẹsẹ̀ yín (12-17) Wọ́n sún mọ́ Jerúsálẹ́mù ti ọ̀run (18-29) 13 Ọ̀rọ̀ ìyànjú àti ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (1-25) Ẹ má gbàgbé láti máa ṣe aájò àlejò (2) Kí ìgbéyàwó ní ọlá (4) Ẹ máa ṣègbọràn sí àwọn tó ń mú ipò iwájú (7, 17) Ẹ máa rú ẹbọ ìyìn (15, 16) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Hébérù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Hébérù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Hébérù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Hébérù ojú ìwé 1595-1596