YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 17 18 19 20 21 22 23 24 Ìwé Jóṣúà Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 17 18 19 20 21 22 23 24 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Jèhófà fún Jóṣúà níṣìírí (1-9) Máa fi ohùn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ ka Òfin (8) Wọ́n ń múra láti sọdá Jọ́dánì (10-18) 2 Jóṣúà rán amí méjì lọ sí Jẹ́ríkò (1-3) Ráhábù fi àwọn amí pa mọ́ (4-7) Wọ́n ṣèlérí fún Ráhábù (8-21a) Okùn aláwọ̀ rírẹ̀dòdò máa jẹ́ àmì (18) Àwọn amí pa dà sọ́dọ̀ Jóṣúà (21b-24) 3 Ísírẹ́lì sọdá Jọ́dánì (1-17) 4 Àwọn òkúta tó máa jẹ́ ohun ìrántí (1-24) 5 Wọ́n dádọ̀dọ́ ní Gílígálì (1-9) Wọ́n ṣe Ìrékọjá; mánà ò rọ̀ mọ́ (10-12) Olórí àwọn ọmọ ogun Jèhófà (13-15) 6 Ògiri Jẹ́ríkò wó lulẹ̀ (1-21) Wọ́n dá ẹ̀mí Ráhábù àti ìdílé rẹ̀ sí (22-27) 7 Wọ́n ṣẹ́gun Ísírẹ́lì ní ìlú Áì (1-5) Àdúrà Jóṣúà (6-9) Ẹ̀ṣẹ̀ mú kí wọ́n ṣẹ́gun Ísírẹ́lì (10-15) Àṣírí Ákánì tú, wọ́n sì sọ ọ́ lókùúta (16-26) 8 Jóṣúà ní kí wọ́n lúgọ láti gbéjà ko ìlú Áì (1-13) Wọ́n ṣẹ́gun ìlú Áì (14-29) Wọ́n ka Òfin ní Òkè Ébálì (30-35) 9 Àwọn ará Gíbíónì dọ́gbọ́n wá àlàáfíà (1-15) Àṣírí àwọn ará Gíbíónì tú (16-21) Àwọn ará Gíbíónì á máa ṣẹ́gi, wọ́n á sì máa pọnmi (22-27) 10 Ísírẹ́lì gbèjà Gíbíónì (1-7) Jèhófà jà fún Ísírẹ́lì (8-15) Òkúta yìnyín já bọ́ lu àwọn ọ̀tá tó ń sá lọ (11) Oòrùn dúró sójú kan (12-14) Wọ́n pa ọba márààrún tó gbéjà kò wọ́n (16-28) Wọ́n gba àwọn ìlú tó wà ní gúúsù (29-43) 11 Wọ́n gba àwọn ìlú tó wà ní àríwá (1-15) Àwọn ilẹ̀ tí Jóṣúà ṣẹ́gun (16-23) 12 Wọ́n ṣẹ́gun àwọn ọba ìlà oòrùn Jọ́dánì (1-6) Wọ́n ṣẹ́gun àwọn ọba ìwọ̀ oòrùn Jọ́dánì (7-24) 13 Àwọn ilẹ̀ tí wọn ò tíì gbà (1-7) Wọ́n pín ilẹ̀ tó wà ní ìlà oòrùn Jọ́dánì (8-14) Ogún Rúbẹ́nì (15-23) Ogún Gádì (24-28) Ogún Mánásè ní ìlà oòrùn (29-32) Jèhófà ni ogún àwọn ọmọ Léfì (33) 14 Wọ́n pín ilẹ̀ tó wà ní ìwọ̀ oòrùn Jọ́dánì (1-5) Kélẹ́bù jogún Hébúrónì (6-15) 15 Ogún Júdà (1-12) Ọmọbìnrin Kélẹ́bù gba ilẹ̀ (13-19) Àwọn ìlú Júdà (20-63) 16 Ogún àwọn àtọmọdọ́mọ Jósẹ́fù (1-4) Ogún Éfúrémù (5-10) 17 Ogún Mánásè ní ìwọ̀ oòrùn (1-13) Àwọn àtọmọdọ́mọ Jósẹ́fù tún gba ilẹ̀ míì (14-18) 18 Wọ́n pín ilẹ̀ tó kù ní Ṣílò (1-10) Ogún Bẹ́ńjámínì (11-28) 19 Ogún Síméónì (1-9) Ogún Sébúlúnì (10-16) Ogún Ísákà (17-23) Ogún Áṣérì (24-31) Ogún Náfútálì (32-39) Ogún Dánì (40-48) Ogún Jóṣúà (49-51) 20 Àwọn ìlú ààbò (1-9) 21 Àwọn ìlú tí wọ́n fún àwọn ọmọ Léfì (1-42) Ìlú àwọn àtọmọdọ́mọ Áárónì (9-19) Ìlú àwọn ọmọ Kóhátì yòókù (20-26) Ìlú àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì (27-33) Ìlú àwọn ọmọ Mérárì (34-40) Àwọn ìlérí Jèhófà ṣẹ (43-45) 22 Àwọn ẹ̀yà tó wà ní ìlà oòrùn pa dà sílé (1-8) Wọ́n mọ pẹpẹ sí Jọ́dánì (9-12) Wọ́n ṣàlàyé ohun tí pẹpẹ náà túmọ̀ sí (13-29) Wọ́n yanjú ọ̀rọ̀ náà (30-34) 23 Jóṣúà sọ̀rọ̀ ìdágbére fún àwọn olórí Ísírẹ́lì (1-16) Ìkankan nínú ọ̀rọ̀ Jèhófà ò kùnà (14) 24 Jóṣúà sọ ìtàn Ísírẹ́lì (1-13) Ó rọ̀ wọ́n pé kí wọ́n sin Jèhófà (14-24) “Ní tèmi àti agbo ilé mi, Jèhófà ni àwa yóò máa sìn” (15) Jóṣúà bá Ísírẹ́lì dá májẹ̀mú (25-28) Jóṣúà kú, wọ́n sì sin ín (29-31) Wọ́n sin egungun Jósẹ́fù sí Ṣékémù (32) Élíásárì kú, wọ́n sì sin ín (33) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Jóṣúà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Jóṣúà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Jóṣúà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Jóṣúà ojú ìwé 316-317