YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 Ìwé Náhúmù Orí 1 2 3 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ọlọ́run máa gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá rẹ̀ (1-7) Ọlọ́run fẹ́ kí a máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo (2) Jèhófà mọ àwọn tó ń wá ibi ààbò lọ́dọ̀ rẹ̀ (7) Nínéfè máa pa run (8-14) Wàhálà kò ní dìde lẹ́ẹ̀kejì (9) Ìròyìn ayọ̀ fún Júdà (15) 2 Nínéfè máa pa run (1-13) “Ilẹ̀kùn àwọn odò rẹ̀ máa ṣí sílẹ̀” (6) 3 “Ìlú tó ń ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ gbé!” (1-19) Ìdí tí Ọlọ́run fi máa dá Nínéfè lẹ́jọ́ (1-7) Nínéfè máa ṣubú bíi No-ámónì (8-12) Ó dájú pé Nínéfè máa ṣubú (13-19) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Náhúmù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Náhúmù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Náhúmù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Náhúmù ojú ìwé 1265