Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Lẹ́tà sí Àwọn Ará Róòmù

Orí

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Ìkíni (1-7)

    • Ó wu Pọ́ọ̀lù láti lọ sí Róòmù (8-15)

    • Ìgbàgbọ́ yóò mú kí olódodo wà láàyè (16, 17)

    • Àwọn èèyàn tí kò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run kò ní àwíjàre (18-32)

      • À ń rí àwọn ànímọ́ Ọlọ́run nínú àwọn ohun tó dá (20)

  • 2

    • Ìdájọ́ Ọlọ́run lórí àwọn Júù àti Gíríìkì (1-16)

      • Bí ẹ̀rí ọkàn ṣe ń ṣiṣẹ́ (14, 15)

    • Àwọn Júù àti Òfin (17-24)

    • Ìkọlà ọkàn (25-29)

  • 3

    • “Kí Ọlọ́run jẹ́ olóòótọ́” (1-8)

    • Àwọn Júù àti àwọn Gíríìkì wà lábẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ (9-20)

    • Òdodo nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ (21-31)

      • Gbogbo èèyàn kò kúnjú ìwọ̀n ògo Ọlọ́run (23)

  • 4

    • A pe Ábúráhámù ní olódodo nítorí ìgbàgbọ́ (1-12)

      • Ábúráhámù ni baba àwọn tó ní ìgbàgbọ́ (11)

    • Ìlérí tí a gbà nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ (13-25)

  • 5

    • Èèyàn pa dà bá Ọlọ́run rẹ́ nípasẹ̀ Kristi (1-11)

    • Ikú wá nípasẹ̀ Ádámù, ìyè wá nípasẹ̀ Kristi (12-21)

      • Ẹ̀ṣẹ̀ àti ikú tàn dé ọ̀dọ̀ gbogbo èèyàn (12)

      • Ìwà òdodo kan (18)

  • 6

    • Ìgbé ayé ọ̀tun nípasẹ̀ batisí sínú Kristi (1-11)

    • Ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹ̀ṣẹ̀ jọba nínú ara yín (12-14)

    • Láti ẹrú ẹ̀ṣẹ̀ sí ẹrú Ọlọ́run (15-23)

      • Èrè ẹ̀ṣẹ̀ ni ikú; Ẹ̀bùn Ọlọ́run ni ìyè (23)

  • 7

    • Àpèjúwe bí a ṣe dá wa sílẹ̀ lọ́wọ́ Òfin (1-6)

    • Òfin fi ẹ̀ṣẹ̀ hàn (7-12)

    • Ó ń bá ẹ̀ṣẹ̀ wọ̀yá ìjà (13-25)

  • 8

    • Ìyè àti òmìnira nípasẹ̀ ẹ̀mí (1-11)

    • Ẹ̀mí ìsọdọmọ ń jẹ́rìí (12-17)

    • Ìṣẹ̀dá ń dúró de òmìnira àwọn ọmọ Ọlọ́run (18-25)

    • ‘Ẹ̀mí ń bá wa bẹ̀bẹ̀’ (26, 27)

    • Ọlọ́run yàn wá ṣáájú (28-30)

    • Ìfẹ́ Ọlọ́run mú kí a di aṣẹ́gun (31-39)

  • 9

    • Pọ́ọ̀lù kẹ́dùn nítorí Ísírẹ́lì tara (1-5)

    • Ọmọ Ábúráhámù tòótọ́ (6-13)

    • Ohun tí Ọlọ́run bá yàn, kò sẹ́ni tó lè yí i pa dà (14-26)

      • Ohun èlò ìrunú àti ti àánú (22, 23)

    • Àṣẹ́kù nìkan la ó gbà là (27-29)

    • Ísírẹ́lì kọsẹ̀ (30-33)

  • 10

    • Bí ọwọ́ èèyàn ṣe lè tẹ òdodo Ọlọ́run (1-15)

      • Ìkéde ní gbangba (10)

      • Kíképe Jèhófà ń yọrí sí ìgbàlà (13)

      • Ẹsẹ̀ àwọn oníwàásù rẹwà (15)

    • Wọ́n kọ ìhìn rere (16-21)

  • 11

    • Ọlọ́run ò kọ Ísírẹ́lì sílẹ̀ pátápátá (1-16)

    • Àpèjúwe igi ólífì (17-32)

    • Ọgbọ́n Ọlọ́run mà jinlẹ̀ o (33-36)

  • 12

    • Ẹ fi ara yín fún Ọlọ́run ní ẹbọ ààyè (1, 2)

    • Ẹ̀bùn ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀, àmọ́ ara kan náà (3-8)

    • Ìmọ̀ràn lórí ìgbé ayé Kristẹni tòótọ́ (9-21)

  • 13

    • Ìtẹríba fún àwọn aláṣẹ (1-7)

    • Ìfẹ́ ni àkójá Òfin (8-10)

    • Máa rìn bí ìgbà téèyàn ń rìn ní ọ̀sán (11-14)

  • 14

    • Má ṣe dá ọmọnìkejì rẹ lẹ́jọ́ (1-12)

    • Má ṣe mú ẹlòmíì kọsẹ̀ (13-18)

    • Mú kí àlàáfíà àti ìṣọ̀kan wà (19-23)

  • 15

    • Ẹ tẹ́wọ́ gba ara yín bí Kristi ti ṣe (1-13)

    • Pọ́ọ̀lù, ìránṣẹ́ àwọn orílẹ̀-èdè (14-21)

    • Àwọn ibi tí Pọ́ọ̀lù fẹ́ rìnrìn àjò lọ (22-33)

  • 16

    • Pọ́ọ̀lù sọ̀rọ̀ nípa Fébè tó jẹ́ òjíṣẹ́ (1, 2)

    • Wọ́n ń kí àwọn Kristẹni tó wà ní Róòmù (3-16)

    • Ìkìlọ̀ pé kí wọ́n yẹra fún ìyapa (17-20)

    • Àwọn tó ń bá Pọ́ọ̀lù ṣiṣẹ́ kí àwọn ará (21-24)

    • A ti wá mọ àṣírí mímọ́ (25-27)