A7-B
Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Ìbẹ̀rẹ̀ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Jésù
ÀKÓKÒ |
IBI |
ÌṢẸ̀LẸ̀ |
MÁTÍÙ |
MÁÀKÙ |
LÚÙKÙ |
JÒHÁNÙ |
---|---|---|---|---|---|---|
29, ìgbà ìwọ́wé |
Odò Jọ́dánì, bóyá ní Bẹ́tánì tàbí nítòsí ibẹ̀, ní ìsọdá Jọ́dánì |
Jésù ṣe ìrìbọmi, Ọlọ́run sì fi ẹ̀mí mímọ́ yàn án; Jèhófà sọ pé Ọmọ òun ni, ó sì tẹ́wọ́ gbà á |
||||
Aginjù Jùdíà |
Èṣù dán an wò |
|||||
Bẹ́tánì ní ìsọdá Jọ́dánì |
Jòhánù Arinibọmi fi Jésù hàn pé ó jẹ́ Ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run; àwọn ọmọ ẹ̀yìn àkọ́kọ́ dara pọ̀ mọ́ Jésù |
|||||
Kánà ti Gálílì; Kápánáúmù |
Iṣẹ́ ìyanu àkọ́kọ́ níbi ìgbéyàwó, ó sọ omi di wáìnì; ó lọ sí Kápánáúmù |
|||||
30, Ìrékọjá |
Jerúsálẹ́mù |
Ó fọ tẹ́ńpìlì mọ́ |
||||
Ó bá Nikodémù sọ̀rọ̀ |
||||||
Jùdíà; Áínónì |
Ó lọ sí ìgbèríko Jùdíà, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ ń ṣèrìbọmi fún àwọn èèyàn; ẹ̀rí tí Jòhánù jẹ́ kẹ́yìn nípa Jésù |
|||||
Tìbéríà; Jùdíà |
Wọ́n fi Jòhánù sẹ́wọ̀n; Jésù lọ sí Gálílì |
|||||
Síkárì, ní Samáríà |
Nígbà tó ń lọ sí Gálílì, ó kọ́ àwọn ará Samáríà |