Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

B8

Tẹ́ńpìlì Tí Sólómọ́nì Kọ́

  1. Àwọn Ohun Tó Wà ní Tẹ́ńpìlì

  2.  1 Ibi Mímọ́ Jù Lọ (1Ọb 6:16, 20)

  3.  2 Ibi Mímọ́ (2Kr 5:9)

  4.  3 Àwọn Yàrá Orí Òrùlé (2Kr 3:8, 9)

  5.  4 Àwọn Yàrá Ẹ̀gbẹ́ (1Ọb 6:5, 6, 10)

  6.  5 Jákínì (1Ọb 7:21; 2Kr 3:17)

  7.  6 Bóásì (1Ọb 7:21; 2Kr 3:17)

  8.  7 Ibi Àbáwọlé (1Ọb 6:3; 2Kr 3:4)

  9.  8 Pẹpẹ Bàbà (2Kr 4:1)

  10.  9 Pèpéle Bàbà (2Kr 6:13)

  11. 10 Àgbàlá Inú (1Ọb 6:36)

  12. 11 Òkun Tí Wọ́n Fi Irin Ṣe (1Ọb 7:23)

  13. 12 Àwọn Kẹ̀kẹ́ Ẹrù (1Ọb 7:27)

  14. 13 Ẹnu Ọ̀nà Ẹ̀gbẹ́ (1Ọb 6:8)

  15. 14 Àwọn Yàrá Ìjẹun (1Kr 28:12)