YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 Lẹ́tà Jémíìsì Orí 1 2 3 4 5 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ìkíni (1) Ìfaradà ń jẹ́ ká láyọ̀ (2-15) A máa ń dán ìgbàgbọ́ wò ní ti bó ṣe jẹ́ ojúlówó tó (3) Ẹ máa fi ìgbàgbọ́ béèrè (5-8) Ìfẹ́ ọkàn máa ń yọrí sí ẹ̀ṣẹ̀ àti ikú (14, 15) Gbogbo ẹ̀bùn rere wá láti òkè (16-18) Olùgbọ́ àti olùṣe ọ̀rọ̀ náà (19-25) Ẹni tó ń wo ara rẹ̀ nínú dígí (23, 24) Ìjọsìn tó mọ́, tí kò sì ní ẹ̀gbin (26, 27) 2 Ojúsàájú jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ (1-13) Ìfẹ́ ni ọba òfin (8) Ìgbàgbọ́ láìsí àwọn iṣẹ́ jẹ́ òkú (14-26) Àwọn ẹ̀mí èṣù gbà, jìnnìjìnnì sì bò wọ́n (19) A pe Ábúráhámù ní ọ̀rẹ́ Jèhófà (23) 3 Bí a ṣe lè kápá ahọ́n (1-12) Kí ọ̀pọ̀ má ṣe di olùkọ́ (1) Ọgbọ́n tó wá láti òkè (13-18) 4 Ẹ má ṣe jẹ́ ọ̀rẹ́ ayé (1-12) Ẹ dojú ìjà kọ Èṣù (7) Ẹ sún mọ́ Ọlọ́run (8) Ìkìlọ̀ pé ká má ṣe gbéra ga (13-17) “Tí Jèhófà bá fẹ́” (15) 5 Ìkìlọ̀ fún àwọn ọlọ́rọ̀ (1-6) Ọlọ́run ń bù kún àwọn tó ní sùúrù àti ìfaradà (7-11) Ẹ jẹ́ kí “bẹ́ẹ̀ ni” yín jẹ́ bẹ́ẹ̀ ni (12) Àdúrà ìgbàgbọ́ lágbára (13-18) Ran ẹlẹ́ṣẹ̀ lọ́wọ́ kó lè yí pa dà (19, 20) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Jémíìsì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Jémíìsì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Jémíìsì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Jákọ́bù ojú ìwé 1610