October 14-20
SÁÀMÙ 96-99
Orin 66 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
1. “Ẹ Máa Kéde Ìhìn Rere”!
(10 min.)
Máa sọ ìhìn rere náà fáwọn èèyàn (Sm 96:2; w11 3/1 6 ¶1-2)
Sọ ìròyìn ayọ̀ nípa Ọjọ́ Ìdájọ́ fún wọn (Sm 96:12, 13; w12 9/1 16 ¶1)
Jẹ́ kí wọ́n mọ̀ pé ohun tó jẹ́ ìfẹ́ Ọlọ́run ni pé kí àwọn èèyàn táá máa yin orúkọ rẹ̀ kún ayé (Sm 99:1-3; w12 9/15 12 ¶18-19)
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
Sm 96:1—Láwọn ibi tí ọ̀rọ̀ náà “orin tuntun” ti fara hàn nínú Bíbélì, kí ló sábà máa ń túmọ̀ sí? (it-2 994)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Sm 98:1–99:9 (th ẹ̀kọ́ 11)
4. Fọwọ́ Pàtàkì Mú Ìkẹ́kọ̀ọ́—Ohun Tí Jésù Ṣe
(7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò lmd ẹ̀kọ́ 10 kókó 1-2.
5. Fọwọ́ Pàtàkì Mú Ìkẹ́kọ̀ọ́—Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù
(8 min.) Ìjíròrò tó dá lórí lmd ẹ̀kọ́ 10 kókó 3-5 àti “Tún Wo.”
Orin 9
6. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ
(15 min.)
7. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) bt orí 16 ¶10-18