Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ ‘Ẹ Máa Wá Àlàáfíà’! Ti Ọdún 2022
Friday
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Friday dá lórí Sáàmù 29:11—“Jèhófà yóò fi àlàáfíà jíǹkí àwọn èèyàn rẹ̀.”
Saturday
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Saturday dá lórí 2 Pétérù 3:14—“Ẹ sa gbogbo ipá yín kó lè bá yín . . . láìní èérí àti àbààwọ́n àti ní àlàáfíà.”
Sunday
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Sunday dá lórí Róòmù 15:13—“Kí Ọlọ́run tó ń fúnni ní ìrètí fi gbogbo ayọ̀ àti àlàáfíà kún inú yín.”
Ohun Tá A Fẹ́ Kí Àwọn Tó Wá sí Àpéjọ Yìí Mọ̀
Ìsọfúnni fáwọn tó bá wá.