Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ‘Ẹ Máa Ní Sùúrù’! ti Ọdún 2023

Friday

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Friday dá lórí 1 Kọ́ríńtì 13:4​—“Ìfẹ́ máa ń ní sùúrù.”

Saturday

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Saturday dá lórí 1 Tẹsalóníkà 5:14​—“Ẹ máa mú sùúrù fún gbogbo èèyàn.”

Sunday

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Sunday dá lórí Àìsáyà 30:18​—“Jèhófà ń fi sùúrù dúró láti ṣojúure sí yín.”

Ohun tá a fẹ́ kí àwọn tó wá sí àpéjọ yìí mọ̀

Ohun tá a fẹ́ kí àwọn tó wá sí àpéjọ yìí mọ̀.

O Tún Lè Wo

NÍPA WA

Lọ Sí Àpéjọ tọdún 2024​—‘Ẹ Máa Kéde Ìhìn Rere!’

A fẹ́ kó o wá sí àpéjọ ọlọ́jọ́ mẹ́ta táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ṣe.

ÀPÉJỌ

A Fẹ́ Kó O Wá Sí Àpéjọ ‘Ẹ Máa Ní Sùúrù’! ti Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti Ọdún 2023

A pè ẹ́ wá sí àpéjọ ọlọ́jọ́ mẹ́ta tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ṣe.