Ìsọfúnni Ṣókí—Nigeria
- 222,182,000—Iye àwọn èèyàn
- 400,375—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 6,071—Iye àwọn ìjọ
- 589—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
Àwọn Ará Ń Gbádùn Tẹlifíṣọ̀n JW Láwọn Ibi Tí Ò Ti Sí Íńtánẹ́ẹ̀tì
Báwo làwọn ará ní Áfíríkà ṣe ń wo ètò tẹlifíṣọ̀n JW láìlo íńtánẹ́ẹ̀tì?
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Àpẹẹrẹ Àwọn Ẹni Tẹ̀mí Mú Kí N Fayé Mi Sin Jèhófà
Ka ìtàn ìgbésí ayé Woodworth Mills, kó o sì rí bó ṣe fayé rẹ̀ sin Jèhófà fún nǹkan bí ọgọ́rin (80) ọdún.