Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Norway

  • Finnmarksvidda, Norway​—Wọ́n ń wàásù ní ilẹ̀ ìbílẹ̀ àwọn Sami

  • Ranheim, Norway​—Showing the video Why Study the Bible? with the northern lights in the background

  • Finnmarksvidda, Norway​—Wọ́n ń wàásù ní ilẹ̀ ìbílẹ̀ àwọn Sami

  • Ranheim, Norway​—Showing the video Why Study the Bible? with the northern lights in the background

Ìsọfúnni Ṣókí—Norway

  • 5,504,000—Iye àwọn èèyàn
  • 12,034—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 162—Iye àwọn ìjọ
  • 464—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—ní Norway

Báwo ni ìbéèrè kan tó wá láìròtẹ́lẹ̀ ṣe mú kí ìdílé kan kó lọ síbi tá a ti nílò àwọn oníwàásù púpọ̀ sí i?