Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwọn Ìsọfúnni Kéékèèké àti Àwọn Ohun Míì Tó Jọ Ọ́ Tí BA.JW.ORG Ń Lò

Àwọn Ìsọfúnni Kéékèèké àti Àwọn Ohun Míì Tó Jọ Ọ́ Tí BA.JW.ORG Ń Lò

Oríṣiríṣi ìsọfúnni kéékèèké ló wà, iṣẹ́ wọn sì yàtọ̀ síra, àmọ́ gbogbo wọn ló máa jẹ́ kó o lè gbádùn ìkànnì yìí. Àpẹẹrẹ bá a ṣe ń lo àwọn ìsọfúnni kéékèèké àtàwọn ohun míì tó jọ ọ́ ló wà nísàlẹ̀ yìí.

Orúkọ

Ìdì

Ìgbà a

Oríṣi

_pk_id.*

A máa ń fi gba ìsọfúnni nípa bí ẹnì kan ṣe ń lo ìkànnì kan. A máa wá fi ìsọfúnni yìí ṣàkójọ báwọn èèyàn ṣe ń lo ìkànnì náà sí, àá sì fi mú kí ìkànnì náà sunwọ̀n sí i. A kì í béèrè kúlẹ̀kúlẹ̀ nípa ẹni tó ń lo ìkànnì náà, ìsọfúnni tá a máa ń gbà ò ju irú browser tó ń lò, irú fóònù tàbí kọ̀ǹpútà tó ń lò, ibi tó ti ń lo ìkànnì náà, iye ìgbà tó ti lo ìkànnì náà tàbí apá kan níbẹ̀ àti bó ṣe máa ń pẹ́ tó láwọn apá ibì kan lórí ìkànnì náà.

Ọdún méjì

Ìsọfúnni Tá A Fi Ń Ṣèwádìí

balogCache.data, .keys

Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan rí ìsọfúnni gbà tó bá ṣẹlẹ̀ pé ìṣòro tàbí àṣìṣe wà.

Lọ́wọ́lọ́wọ́

(tó bá ń lo ìkànnì náà lọ́wọ́)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

adal.*

A fi máa ń tọ́jú ìsọfúnni tẹ́nì kan lè fi wọlé.

Lọ́wọ́lọ́wọ́

(tó bá ń lo ìkànnì náà lọ́wọ́)

Ìsọfúnni Tó Pọn Dandan

BA

A fi máa ń mọ̀ bóyá Safari ni browser tó ń lò àbí òun kọ́.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage))

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

CurrentCulture

Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè rí abala kan ní èdè rẹ̀.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

ba.authenticationCache.*

A fi máa ń tọ́jú ìsọfúnni nípa ibi tí ẹnì kan lè dé lórí ìkànnì náà àti ohun tó lè ṣe ní ibì kọ̀ọ̀kan.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

ba.languageCache.*

Ó máa ń jẹ́ kí ẹnì kan yára yan orúkọ èdè.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

ba.purposeTagCache.*

Ó máa ń jẹ́ kí ẹnì kan lè tún purpose tag lò.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

ba.stringsCache.*

A máa ń fi rántí ohun tó jẹ mọ́ èdè tá a fẹ́ túmọ̀.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

ba.tradeSkillCache.*

Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè tún trade skill lò.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

ba.tradeTagCache.*

Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè tún trade tag lò.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

cache_version

A fi máa ń wọ́gi lé ìsọfúnni kan tá a ti tọ́jú tẹ́lẹ̀, àmọ́ tí kò tọ̀nà.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

language_cache

Ó máa ń jẹ́ kí ẹnì kan yára yan orúkọ èdè.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

loadedStaticLanguage

Ó máa ń jẹ́ ká lè tọ́jú ìsọfúnni nípa èdè abala tẹ́nì kan ń lò lórí ìkànnì náà.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

purposetag_cache

Ó máa ń jẹ́ kí ẹnì kan lè tún purpose tag lò.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

trade_cache

Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè tún trade skill lò.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

tradetag_cache

Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè tún trade tag lò.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

version

Ó máa jẹ́ ká lè tọ́jú ìsọfúnni nípa ìkànnì náà tá à ń fi hàn, tá a sì lè fi wọ́gi lé ìsọfúnni tí kò tọ̀nà.

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

ba.persistentCache.*

Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè lo ètò tó tọ̀nà (bí ètò paging àti selected tab).

Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

my_locale

Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè rí abala tó ń lò ní èdè tó tọ́.

Oṣù mẹ́fà

Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì

Tún wo Àwọn Ìsọfúnni Kéékèèké àti Àwọn Ohun Míì Tó Jọ Ọ́ Tí Àwọn Ìkànnì Wa Ń Lò.

a Tá a bá sọ pé ìsọfúnni kan jẹ́ èyí tí “Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)”, ohun tá à ń sọ ni pé orí ìkànnì wa kọ́ ni ìsọfúnni náà máa pa mọ́ sí, orí browser tí ẹni náà fi ń lọ sórí ìkànnì ni. Torí náà, irú àwọn ìsọfúnni yìí kì í lọ́jọ́ tó máa pa rẹ́, torí ó máa wà lórí browser yẹn títí, àfi tí ẹni náà bá pa àwọn ìsọfúnni tó wà lórí browser ẹ̀ rẹ́.