Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Azerbaijan

 

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Orílẹ̀-èdè Azerbaijan

  • Iye àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà​—1,674

  • Iye àwọn ìjọ​—18

  • Iye àwọn tó wá síbi Ìrántí Ikú Kristi​—3,647

  • Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún​—6,118

  • Iye èèyàn​—10,156,000

2018-04-23

AZERBAIJAN

Ilé Ẹjọ́ Lórílẹ̀-èdè Azerbaijan Ní Kí Wọ́n Sanwó Gbà-máà-bínú fún Irina Zakharchenko àti Valida Jabrayilova

Ilé ẹjọ́ kan nílùú Baku ní Azerbaijan sọ pé kí wọ́n sanwó gbà-máà-bínú fún àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà méjì táwọn aláṣẹ fi sẹ́wọ̀n láìtọ́ fún oṣù mọ́kànlá.

2017-06-12

AZERBAIJAN

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Káwọn Aláṣẹ ní Azerbaijan Dá Àwọn tí Wọ́n Tì Mọ́lé Láìṣẹ̀ Sílẹ̀

Ṣe ni wọ́n ń fìyà jẹ Irina Zakharchenko àti Valida Jabrayilova bíi pé ọ̀daràn paraku ni wọ́n, torí pé wọ́n ń sọ ohun tí wọ́n gbà gbọ́ fáwọn míì. Ìjọba Azerbaijan sì ti sọ pé àwọn ò ní ṣe ẹ̀tanú ẹ̀sìn. Ṣé wọ́n máa wá kó ọ̀rọ̀ wọn jẹ ni?